Kronika Kinni 27:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Jaṣobeamu, ọmọ Sabidieli, ni olórí ìpín kinni, fún oṣù kinni; iye àwọn tí wọ́n wà ninu ìpín rẹ̀ jẹ́ ọ̀kẹ́ kan ó lé ẹgbaaji.

Kronika Kinni 27

Kronika Kinni 27:1-3