Kronika Kinni 27:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Balogun tí ó wà fún oṣù kejila ni Helidai ará Netofati, láti inú ìran Otinieli; iye àwọn tí wọ́n wà ninu ìpín rẹ̀ jẹ́ ọ̀kẹ́ kan ó lé ẹgbaaji (24,000).

Kronika Kinni 27

Kronika Kinni 27:12-24