Kronika Kinni 27:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Balogun tí ó wà fún oṣù kẹwaa ni Maharai, ará Netofa láti inú ìran Serahi; iye àwọn tí wọ́n wà ninu ìpín rẹ̀ jẹ́ ọ̀kẹ́ kan ó lé ẹgbaaji (24,000).

Kronika Kinni 27

Kronika Kinni 27:5-17