Kronika Kinni 27:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Balogun tí ó wà fún oṣù kẹjọ ni Sibekai, ará Huṣa, láti inú ìran Serahi; iye àwọn tí wọ́n wà ninu ìpín rẹ̀ jẹ́ ọ̀kẹ́ kan ó lé ẹgbaaji (24,000).

Kronika Kinni 27

Kronika Kinni 27:10-19