Kronika Kinni 26:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Ninu ìdílé Iṣari, Kenanaya ati àwọn ọmọ rẹ̀ ni wọ́n yàn ní alákòóso ati onídàájọ́ fún àwọn ọmọ Israẹli.

Kronika Kinni 26

Kronika Kinni 26:27-32