Kronika Kinni 26:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Ninu àwọn ìkógun tí wọ́n kó lójú ogun, wọ́n ya àwọn ẹ̀bùn kan sọ́tọ̀ fún ìtọ́jú ilé OLUWA.

Kronika Kinni 26

Kronika Kinni 26:25-32