Kronika Kinni 26:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Ninu àwọn arakunrin Ṣebueli, láti ìdílé Elieseri, a yan Rehabaya ọmọ Elieseri, Jeṣaaya ọmọ Rehabaya, Joramu ọmọ Jeṣaaya, Sikiri ọmọ Joramu ati Ṣelomiti ọmọ Sikiri.

Kronika Kinni 26

Kronika Kinni 26:21-32