Kronika Kinni 26:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Hosa, láti inú ìran Merari bí ọmọkunrin mẹrin: Ṣimiri (ni baba rẹ̀ fi ṣe olórí, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé kì í ṣe òun ni àkọ́bí);

Kronika Kinni 26

Kronika Kinni 26:2-14