Kronika Kinni 25:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Àpapọ̀ wọn pẹlu àwọn arakunrin wọn, tí a ti kọ́ ní orin kíkọ sí OLUWA, ati lílo ohun èlò orin, jẹ́ ọọdunrun ó dín mejila (288).

Kronika Kinni 25

Kronika Kinni 25:4-15