Kronika Kinni 25:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Lára àwọn ọmọ Asafu wọ́n yan Sakuri, Josẹfu, Netanaya, ati Asarela; wọ́n wà lábẹ́ àkóso Asafu, wọn a sì máa sọ àsọtẹ́lẹ̀ lábẹ́ àkóso ọba.

Kronika Kinni 25

Kronika Kinni 25:1-4