Kronika Kinni 24:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ Heburoni jẹ́ mẹrin: Jeraya ni olórí wọn, bí àwọn yòókù wọn ṣe tẹ̀léra nìyí: Amaraya, Jahasieli ati Jekameamu.

Kronika Kinni 24

Kronika Kinni 24:19-27