Kronika Kinni 24:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn olórí ninu ìdílé àwọn ọmọ Lefi yòókù nìwọ̀nyí: Ṣubaeli láti inú ìdílé Amramu,Jedeaya láti inú ìdílé Ṣubaeli.

Kronika Kinni 24

Kronika Kinni 24:18-24