Kronika Kinni 24:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Nadabu ati Abihu kú ṣáájú baba wọn láì bí ọmọ kankan. Nítorí náà, Eleasari, ati Itamari di alufaa.

Kronika Kinni 24

Kronika Kinni 24:1-8