Kronika Kinni 23:6-9 BIBELI MIMỌ (BM)

6. Dafidi pín àwọn ọmọ Lefi ní ìdílé ìdílé: ti Geriṣomu, ti Kohati, ati ti Merari.

7. Àwọn ọmọ Geriṣomu jẹ́ meji: Ladani ati Ṣimei;

8. Àwọn ọmọ Ladani jẹ́ mẹta: Jeieli tí ó jẹ́ olórí, Setamu ati Joẹli.

9. Àwọn ọmọ Ṣimei ni Ṣelomoti, Hasieli, ati Harani; àwọn ni wọ́n jẹ́ olórí ìdílé Ladani.

Kronika Kinni 23