Kronika Kinni 23:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi fún ẹgbaa mejila (24,000) ninu wọn ní iṣẹ́ ninu tẹmpili; ó ní kí ẹgbaata (6,000) máa ṣe àkọsílẹ̀ ati ìdájọ́ àwọn eniyan,

Kronika Kinni 23

Kronika Kinni 23:1-10