Kronika Kinni 23:32 BIBELI MIMỌ (BM)

Bẹ́ẹ̀ ni wọn yóo ṣe máa bojútó Àgọ́ Àjọ ati ibi mímọ́, tí wọn yóo sì máa ran àwọn ọmọ Aaroni, àwọn arakunrin wọn lọ́wọ́, níbi iṣẹ́ ìsìn ilé OLUWA.

Kronika Kinni 23

Kronika Kinni 23:29-32