Kronika Kinni 23:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Elieseri bí ọmọkunrin kan tí ń jẹ́ Rehabaya, olórí ìdílé rẹ̀, kò sì bí ọmọ mìíràn mọ́, ṣugbọn àwọn ọmọ Rehabaya pọ̀.

Kronika Kinni 23

Kronika Kinni 23:16-24