Kronika Kinni 21:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, Ọlọrun rán àjàkálẹ̀ àrùn sórí ilẹ̀ Israẹli, àwọn tí wọ́n kú sì jẹ́ ẹgbaa marundinlogoji (70,000) eniyan.

Kronika Kinni 21

Kronika Kinni 21:8-23