Kronika Kinni 20:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ogun mìíràn tún bẹ́ sílẹ̀ pẹlu àwọn ará Filistia, Elihanani, ọmọ Jairi, pa Lahimi, arakunrin Goliati, ará Gati, tí ọ̀kọ̀ rẹ̀ tóbi tó òpó òfì ìhunṣọ.

Kronika Kinni 20

Kronika Kinni 20:2-8