Kronika Kinni 2:46 BIBELI MIMỌ (BM)

Kalebu tún ní obinrin kan tí ń jẹ́ Efa, ó bí ọmọ mẹta fún un: Harani, Mosa ati Gasesi. Harani bí ọmọ kan tí ń jẹ́ Gasesi.

Kronika Kinni 2

Kronika Kinni 2:40-54