Kronika Kinni 2:37-39 BIBELI MIMỌ (BM)

37. Sabadi bí Efiali, Efiali sì bí Obedi.

38. Obedi ni baba Jehu, Jehu sì ni baba Asaraya.

39. Asaraya ni ó bí Helesi, Helesi ni ó sì bí Eleasa.

Kronika Kinni 2