Kronika Kinni 2:34 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣeṣani kò bí ọmọkunrin kankan, kìkì ọmọbinrin ni ó bí; ṣugbọn Ṣeṣani ní ẹrú kan, ará Ijipti, tí ń jẹ́ Jariha.

Kronika Kinni 2

Kronika Kinni 2:31-37