Kronika Kinni 2:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Jerameeli, àkọ́bí Hesironi, bí ọmọkunrin marun-un: Ramu ni àkọ́bí, lẹ́yìn rẹ̀ ni wọ́n bí Buna, Oreni, Osemu, ati Ahija.

Kronika Kinni 2

Kronika Kinni 2:24-33