Kronika Kinni 2:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Hesironi ni baba Kalebu. Asuba (ati Jeriotu) ni aya Kalebu yìí, Asuba bí ọmọkunrin mẹta fún un: Jeseri, Ṣobabu, ati Aridoni.

Kronika Kinni 2

Kronika Kinni 2:11-27