Kronika Kinni 2:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Àwọn ọmọ Israẹli nìwọ̀nyí: Reubẹni, Simeoni, ati Lefi; Juda, Isakari, ati Sebuluni;

2. Dani, Josẹfu, ati Bẹnjamini; Nafutali, Gadi ati Aṣeri.

3. Juda bí ọmọ marun-un. Batiṣua, aya rẹ̀, ará Kenaani, bí ọmọ mẹta fún un: Eri, Onani ati Ṣela. Eri, àkọ́bí Juda, jẹ́ eniyan burúkú lójú OLUWA, OLUWA bá pa á.

Kronika Kinni 2