Kronika Kinni 19:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Dafidi gbọ́, ó kó gbogbo ọmọ ogun Israẹli jọ, wọ́n rékọjá odò Jọdani, wọ́n lọ dojú kọ ogun Siria, àwọn ọmọ ogun Siria bá bẹ̀rẹ̀ sí bá Dafidi jagun.

Kronika Kinni 19

Kronika Kinni 19:15-19