Kronika Kinni 18:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí àwọn ará Siria wá láti Damasku, láti ran Hadadeseri, ọba Soba lọ́wọ́, Dafidi gbógun tì wọ́n, ó sì pa ẹgbaa mọkanla (22,000) ninu àwọn ọmọ ogun wọn.

Kronika Kinni 18

Kronika Kinni 18:1-13