Kronika Kinni 18:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó fi àwọn ọmọ ogun sí Edomu, gbogbo àwọn ará Edomu sì di iranṣẹ Dafidi. OLUWA fún Dafidi ní ìṣẹ́gun ní gbogbo ibi tí ó lọ.

Kronika Kinni 18

Kronika Kinni 18:7-14