Kronika Kinni 18:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, Dafidi gbógun ti àwọn Filistini, ó ṣẹgun wọn, ó sì jagun gba ìlú Gati ati àwọn ìletò agbègbè rẹ̀ lọ́wọ́ wọn.

Kronika Kinni 18

Kronika Kinni 18:1-9