Kronika Kinni 17:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Kò sí ẹni tí ó dàbí rẹ, OLUWA, kò sì sí Ọlọrun mìíràn lẹ́yìn rẹ, gẹ́gẹ́ bí ohun tí a ti fi etí wa gbọ́.

Kronika Kinni 17

Kronika Kinni 17:16-24