Kronika Kinni 17:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi bá lọ jókòó níwájú OLUWA, ó gbadura báyìí pé, “Kí ni èmi ati ilé mi jẹ́, tí o fi gbé mi dé ipò tí mo dé yìí?

Kronika Kinni 17

Kronika Kinni 17:7-19