Kronika Kinni 16:41 BIBELI MIMỌ (BM)

Hemani wà pẹlu wọn, ati Jedutuni ati àwọn mìíràn tí a yàn, tí a sì dárúkọ, láti máa dúpẹ́ lọ́wọ́ OLUWA nítorí ìfẹ́ ńlá rẹ̀ tí kì í yẹ̀.

Kronika Kinni 16

Kronika Kinni 16:38-43