Kronika Kinni 16:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó sì yan àwọn ọmọ Lefi kan láti máa ṣe ètò ìsìn níwájú Àpótí Majẹmu OLUWA: láti máa gbadura, láti máa dúpẹ́, ati láti máa yin OLUWA Ọlọrun Israẹli.

Kronika Kinni 16

Kronika Kinni 16:1-9