Kronika Kinni 16:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ ranti gbogbo iṣẹ́ ìyanu rẹ̀,gbogbo nǹkan ìyanu tí ó ṣe, ati gbogbo ìdájọ́ rẹ̀,

Kronika Kinni 16

Kronika Kinni 16:6-19