Kronika Kinni 15:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Iye àwọn ọmọ Lefi tí ó kó jọ láti inú ìdílé kọ̀ọ̀kan nìwọ̀nyí: láti inú ìdílé Kohati: ọgọfa (120) ọkunrin, Urieli ni olórí wọn;

Kronika Kinni 15

Kronika Kinni 15:1-15