Kronika Kinni 15:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, Dafidi pe gbogbo àwọn ọmọ Israẹli sí Jerusalẹmu, kí wọ́n baà lè gbé Àpótí Majẹmu OLUWA wá sí ibi tí ó pèsè sílẹ̀ fún un.

Kronika Kinni 15

Kronika Kinni 15:1-4