Kronika Kinni 15:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Bẹ́ẹ̀ ni gbogbo Israẹli ṣe gbé Àpótí Majẹmu OLUWA pẹlu ìró orin ayọ̀, tí wọn ń fi oríṣìíríṣìí ohun èlò orin bíi ipè, fèrè, aro, hapu ati dùùrù kọ.

Kronika Kinni 15

Kronika Kinni 15:18-29