Kronika Kinni 15:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi ati àwọn àgbààgbà Israẹli ati àwọn olórí ẹgbẹẹgbẹrun ọmọ ogun bá lọ sí ilé Obedi Edomu, wọ́n lọ gbé Àpótí Majẹmu OLUWA pẹlu ayọ̀.

Kronika Kinni 15

Kronika Kinni 15:19-27