Kronika Kinni 15:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà àwọn ọmọ Lefi yan Hemani, ọmọ Joẹli ati Asafu, arakunrin rẹ̀, ọmọ Berekaya, ati àwọn arakunrin wọn láti ìdílé Merari, arakunrin wọn, Etani ọmọ Kuṣaaya.

Kronika Kinni 15

Kronika Kinni 15:9-18