Kronika Kinni 14:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí àwọn ará Filistia gbọ́ pé wọ́n ti fi òróró yan Dafidi lọ́ba lórí Israẹli, gbogbo wọn wá gbógun ti Dafidi. Nígbà tí Dafidi gbọ́, òun náà múra láti lọ gbógun tì wọ́n.

Kronika Kinni 14

Kronika Kinni 14:5-14