Kronika Kinni 14:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí o bá ń gbọ́ ìró ẹsẹ̀ lórí àwọn igi balisamu ni kí o kọlù wọ́n, nítorí pé n óo ṣáájú rẹ lọ láti kọlu ogun Filistini.”

Kronika Kinni 14

Kronika Kinni 14:10-17