Kronika Kinni 13:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà Dafidi kó àwọn ọmọ Israẹli jọ láti Ṣihori ní Ijipti títí dé ẹnubodè Hamati láti lọ gbé Àpótí Majẹmu Ọlọrun láti Kiriati Jearimu lọ sí Jerusalẹmu.

Kronika Kinni 13

Kronika Kinni 13:1-12