Kronika Kinni 12:39 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n wà níbẹ̀ pẹlu Dafidi fún ọjọ́ mẹta, wọ́n ń jẹ, wọ́n ń mu, nítorí àwọn arakunrin wọn ti pèsè oúnjẹ sílẹ̀ dè wọ́n.

Kronika Kinni 12

Kronika Kinni 12:31-40