Kronika Kinni 12:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Láti inú ẹ̀yà Efuraimu, ọ̀kẹ́ kan ó lé ẹgbẹrin (20,800) akikanju ati alágbára, tí wọ́n jẹ́ olókìkí ninu ìdílé wọn ni wọ́n wá.

Kronika Kinni 12

Kronika Kinni 12:23-36