Kronika Kinni 11:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi ní, “Ẹnikẹ́ni tí ó bá kọ́kọ́ pa ará Jebusi kan ni yóo jẹ́ balogun fún àwọn ọmọ ogun mi.” Joabu, ọmọ Seruaya ni ó kọ́kọ́ lọ, ó sì di balogun.

Kronika Kinni 11

Kronika Kinni 11:1-11