Kronika Kinni 11:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi ati àwọn ọmọ Israẹli lọ gbógun ti ìlú Jerusalẹmu, (Jebusi ni orúkọ Jerusalẹmu nígbà náà, ibẹ̀ ni àwọn ará Jebusi ń gbé.)

Kronika Kinni 11

Kronika Kinni 11:3-10