Kronika Kinni 11:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ohun tí Bẹnaya, ọmọ Jehoiada, ṣe nìyí, tí ó sọ ọ́ di olókìkí, yàtọ̀ sí ti àwọn akọni mẹta tí a sọ nípa wọn.

Kronika Kinni 11

Kronika Kinni 11:14-30