Kronika Kinni 1:46 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Huṣamu kú, Hadadi, ọmọ Bedadi, tí ó ṣẹgun àwọn ará Midiani ní ilẹ̀ Moabu, jọba tẹ̀lé e. Orúkọ ìlú rẹ̀ ni Afiti.

Kronika Kinni 1

Kronika Kinni 1:45-53