Kronika Kinni 1:22-28 BIBELI MIMỌ (BM)

22. Ebali, Abimaeli, ati Ṣeba,

23. Ofiri, Hafila ati Jobabu; Àwọn ni àwọn ọmọ Jokitani.

24. Arọmọdọmọ Ṣemu títí fi dé orí Abramu nìyí: Ṣemu, Apakiṣadi, Ṣela;

25. Eberi, Pelegi, Reu;

26. Serugi, Nahori, Tẹra;

27. Abramu, tí a tún ń pè ní Abrahamu.

28. Àwọn ọmọ Abrahamu ni Isaaki ati Iṣimaeli.

Kronika Kinni 1