Kronika Kinni 1:1-6 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Adamu bí Seti, Seti bí Enọṣi.

2. Enọṣi bí Kenaani, Kenaani bí Mahalaleli, Mahalaleli bí Jaredi;

3. Jaredi bí Enọku, Enọku bí Metusela, Metusela bí Lamẹki;

4. Lamẹki bí Noa, Noa bí Ṣemu, Hamu, ati Jafẹti.

5. Àwọn ọmọ Jafẹti ni Gomeri, Magogu, Madai, Jafani, Tubali, Meṣeki ati Tirasi.

6. Gomeri ni baba ńlá àwọn ọmọ Aṣikenasi, Difati ati Togama.

Kronika Kinni 1